Application for the role of a translator in davinci-utopian translation project

utopian_davinci_trad.png

Introduction

I am Adisa Adedapo Jubril, I am Nigerian from Osun State, a predominantly Yoruba language speaking state. I am a graduate of Microbiology from Obafemi Awolowo University and currently self-employed.
As a freelancer with the interest of helping Free and Open Source projects by helping to translate different projects to Yoruba language and to make it more user friendly , I hereby seek the role of a translator which would enable me achieve the said interest.
Having grown up and spent majority of my life in SouthWest Nigeria, I have much experience in reading and writing Yoruba language. English Language being the official Nigeria Language, therefore, I am able to efficiently provide translations between both languages.
I have been privileged to do some translation works on crowdin. My crowdin profile has my activities for references.

Oruko mi ni Adisa Adedapo Jubril, mo je omo bibi orile-ede Naijiria lati Ipinle Osun, Ipinle ti o je pe ede Yoruba siso ni o wopo julo. Mo ti pari ile iwe eko giga agba ti mosi kekogboye imo ijinle sayensi ti Microbiogy lati ile iwe giga Obafemi Awolowo Yunifasiti ti mo si je osise ara mi.
Gegebi osise ara eni ti o ni ife lati ma se iranwo fun awon ise Free and Open Source nipase titumo awon orisiriisi ise si ede Yoruba lati so lilo won di irorun, Nipase eyi mo n gbero lati wa ipo ogbufo eleyi to ma jeki erongba mi di sise.
Leyin ti mo dagba si , ti mo si lo opolopo ninu igbesi aye mi ni guusu-iwo oorun Naijiria, mo ni iriri ti o po ninu k'ika ati k'iko ede Yoruba. Nipase bi ede geesi se je ede apapo orile ede Naijiria, fun idi eyi, mo ni anfaani pupo lati se agbekale itumo laarin awon ede mejeeji pelu irorun.
Mo ti ni anfaani lati se awon ise itumo ede die lori crowdin. Akosile mi lori crowdin yo se afihan awon ohun ti mo ti se seyin fun itokasi.

Previous Translation Works

Crowdin Activities

Audio Proof

https://soundcloud.com/adisa-adedapo/davinci-audio-proof

H2
H3
H4
3 columns
2 columns
1 column
Join the conversation now