In English
My name is Adeniran Victor, i am a graduate of Physics with Electronics, a programmer, photographer and also a computer engineer.
I am a Yoruba, and as such, very well educated in my tribal langauge. It would be a great honour to share that language with the world through translation.
I have spoken yoruba language for over 23 years, i studied it in school for 5 years aside being the most used language at home.
I have intepreted in churches and functions. This is my first time with working utopian.
Ni ede Yoruba
Oruko mi ni Adeniran Victor, mo ka Fisiksi pelu Electronics ni ile eko giga. Mo je kọmputa komputa, ayaworan ati kọmputa ẹlẹrọ.
Mo je omo bibi ile Yoruba, eyen Je kin jafafa ninu ede tabimisi.
A je idununla fun mi lati le pin ede naa pelu araye latise ipa agbounfo.
Mo ti so ede naa fun bi odun metalelogun. Mo ko ede naa ni ile eko fun odun marun. Ati wipe ede naa laun fin soro nile.
Moti gbounfo ni ile ijosin ati ni oode.
Akoko mi re ti ma ba utopian sise
Recording
https://soundcloud.com/adeniran-victor-518425569/translation-for-utopian/s-Klvd3